song lyrics: In lecture halls, mind start to soar a gathering of thoughts, a vibrant score lecturers teach, with passion and love Students listen, attentively In Akungba-Akoko, where university is Adekunle Ajasin, our knowledge ladder with understanding and wisdom, we embark on a beautiful journey, let’s make our mark Library shelves, hold stories and more from science labs, to arts’ embrace goals scored, and victories assure as literatures are read, night and day (blessing fowobaje wish you all success) In Akungba-Akoko, where university is Adekunle Ajasin, our knowledge ladder with understanding and wisdom, we embark on a beautiful journey, let’s make our mark so come to Akungba-Akoko, heed this call to Adekunle Ajasin, wherever you are where minds are, nurtured and trained we’ll paint a picture, that leaves you impressed In Akungba-Akoko, where university is Adekunle Ajasin, our knowledge ladder with understanding and wisdom, we embark on a beautiful journey, let’s make our mark AAUA... Always ni ikówé gbongàn, okàn bèrè latí fofáyò àpéjo tí èrò, oye a lárínrín Awón òlúkoní nkò, ní pèlú ifé àti ohun tí wón ní ìfé sí láti se Awón omo ilé èkó ngbo, nípa fífí etí sílè ní Àkùngbá-Àkókó, níbi tí ilé èkó gíga na wa Adékúnlé Ajásin, níbi tí àkàbà ìmò wa wa pèlú ìmò àti ogbón, a o rín ìrìn àjò eléwà, e jé kí á se ààmí wa Ìkàwé selifu, di awón ìtàn mú àti siwájú sii láti awón ìlé-èkó ìmòjinlé, si ìtéwógbà isé ònà àwón o n tí a rín gbé se, atí ìségun ni idánilojú wa bí a tí ka àwón ìwé, losan ati lóru (ìbùkún fowóbajé gba àdúrà wípe ki gbogbo yín se àséyorí) ní Àkùngbá-Àkókó, níbi tí ilé èkó gíga na wa Adékúnlé Ajásin, níbi tí àkàbà ìmò wa wa pèlú ìmò àti ogbón, a o rín ìrìn àjò eléwà, e jé kí á se ààmí wa fun ìdí eyí wa sí Àkùngbá-Àkókó, gbo ipe yi láti wá sí Adékúnlé Ajásin, láti ibikíbí ti o bá wà níbi tí a tí n tó, okàn àti ìdánilekòó a ó ya àwòrán, kan tí yoo wú o lórí ní Àkùngbá-Àkókó, níbi tí ilé èkó gíga na wa Adékúnlé Ajásin, níbi tí àkàbà ìmò wa wa pèlú ìmò àti ogbón, a o rín ìrìn àjò eléwà, e jé kí á se ààmí wa AAUA... ní gbogbo gba
Hide player controls
Hide resume playing