Ẹ̀jìrẹ́ is a classical folk . A praise poetry, for twins It is an open truth that Africa is the home of twins we sure have them in abundance. Nonetheless, this is dedicated to all twins. Oriki Ibeji (Ẹ̀jìrẹ́) Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún. Ẹdúnjobí Ọmọ ẹdun tíí ṣeré orí igi Ọ́-bẹ́-kẹ́ṣé-bẹ́-kàṣà, Ó fẹsẹ̀ méjèèjì bẹ sílé alákìísa; Ó salákìísà donígba aṣọ......
Hide player controls
Hide resume playing